Cultures and TraditionsYorubaYoruba History

Oriki Ilorin Afonja (Panegyric of Ilorin)

Are Ona Kakanfo Afonja | Oriki Ilorin Afonja
Are-Ona-Kakanfo Afonja of Ilorin

In case you have been searching for the oriki of Ilorin Afonja, you have landed in the right place. Ilorin is a city, traditional emirate and the capital of Kwara State in Southwestern Nigeria. The city is located on the Awun River, a minor tributary of the Niger.

As of the 2006 census, Ilorin had a population of 777,667, making it the 7th largest city by population in Nigeria. Below we present oriki Ilorin Afonja, the panegyric of Ilorin to the descendants of Afonja.

Oriki Ilorin Afonja

Ilorin afonja enudunjuyo

Ilu to jinna s’ina

To sunmon alujana bi aresepa

Ilu tobi to yen, won o leegun rara

Esin l’egungun ile baba won

Akewugberu ni won

A s’adura gbore

Aji fi kalamu da won lekun arise kondu kondu

Won e lu lagbadu

Kewu ni won n ke

Eegun wa bura

Bo ba denu igbo ri

Paka wa bura

Bo ba d’igbale

Ero iwayiopo wa bura

Be o ba l’obirin

Ayidopo laya nle omo egbirin ote

Nile opo omo laderin

Opo korobiti ajagun ajase

Opo k’aja ka r’oyo naa

Abidesu ko je a wo eni to l’oba

Omo opo o gboro

Won pe n koju e s’ina

Ina o gboro

Won pe n koju e s’omi

Omi o gboro

Won pe n fi ponti to le

Oti to le o gboro

Won n f’omo to buru

Omo wo wa lo le tio gboro

Afonja o gboro

Ni won ba koju omo ponilewa s’ogun

Ogun naa l’afonja lo tio pada wa’nule mo

To fi lo te ilu Ilorin

Ilorin afonja ti nje enudunjuyo.

Thanks for reading oriki Ilorin Afonja on OldNaija.com

Cite this article as: Teslim Omipidan. (April 17, 2020). Oriki Ilorin Afonja (Panegyric of Ilorin). OldNaija. Retrieved from https://oldnaija.com/2020/04/17/oriki-ilorin-afonja-panegyric-of-ilorin/

One Comment

 1. This Ilorin panegyric is not very correct especially at the ending. Even though, the whole is a mixture of a bit from the old original and the new one.

  The ending says Àfònjá l’ọmọ tí ò gbọ́ran tí wọ́n kọjú ẹ sí ogun… That’s correct.

  But it continues to say, ‘Ogun náà ni afoja lọ tí kò padà wálé mọ, ‘tó fi lọọ tẹ ìlú Ìlọrin (WRONG)

  Aláàfin of Oyo ‘Oba Aole’ truly sent Àfònjá who was already the 4th Baale in Ilorin and the 6th Aare Ọ̀nà-Kakaǹfo of the whole of the Yorùbá land toe war. He refused to go back to The Aláàfin to give report in an act of rebellion (that’s what it means by ‘ogun náà ni àfònjá lọ tí kò padà wálé mo’)

  It was then that he was also killed by Salih Janta who then took over ILORIN since then.

  Therefore Ilorin has been in existence Àfònjá Himself.

Leave a Reply. OldNaija loves your comment.

Back to top button