Oriki Eko (Eulogy Of Lagos)
To talk of the busiest, most populous and popular city in Nigeria, one would talk of Lagos otherwise known as Eko in the Yoruba language.
Lagos or Eko homes almost if not all Nigerian tribes but is predominantly inhabited by the Awori, a subgroup of the Yoruba people of Southwestern Nigeria and thus earned an Oriki, the Yoruba art of eulogy.
Below is the oriki of Lagos. Enjoy!
Oriki Eko (Eulogy of Lagos)
Eko Akete Ile Ogbon
Eko Aromi sa legbe legbe
Eko aro sese maja
Eko akete ilu okun alagbalugbu omi,
Ta lo ni elomi l’eko?
ebiwon pe talo ni abatabutu baba omikomi,
talo laabata buutu baba odo kodo
Eko adele ti angere nsare ju eniyan elese meji lo
Eni to o ba lo si ilu eko tiko ba gbon,
Koda, bo lo si ilu oyinbo ko legbon mo
Afefe toni pon wa ni bebe okun ti yin,
faaji to ni pan wa ni bebe osa
Eko omo osha nio ose, mase kutere, osha n gbobi, kutere n gbori
Eyin lomo afinju woja marin gbendeke,
obun woja n wapa sio sio
Eyo o Aye’le Eyo o, Eyo baba n teyin to n fi golu n sere,
eyin oni sanwo onibode, odilee
Ti oju o ba ti ehin igbeti, oju o ni t’eko le.
Eko oni baje o
Thanks for reading, OldNaija.com
If you find this useful, kindly share on social media and drop a comment below.
Questions? Advert? Click here to email us.