Old School Naija SongsTraditional Songs

Download Ikoko Akufo – Beautiful Nubia

Download Ikoko Akufo - Beautiful Nubia

If you are looking for where to download Ikoko Akufo by Beautiful Nubia, you have come to the right place.

Beautiful Nubia, born Segun Akinolu in 1968, Ibadan, is a Nigerian songwriter, music composer and bandleader. His Band, Beautiful Nubia and the Roots Renaissance, is widely regarded as Nigeria’s foremost contemporary folk and roots music ensemble.

Below, you can stream and download Ikoko Akufo – Beautiful Nubia (Mp3).

Ikoko akufo, o d’ero akitan o
Ikoko to fo o, o ti dero akitan o
Monomono ya lu’gi, oro wo ‘nu ilu o
Itiju bi aso akisa lo ma ri o
O d’oro agbagba o, o d’eru f’ologbon
O d’owo awon agba o, o d’eru f’ologbonIlu

You Might Also Like

Orita o
Ilu alaafia
Mo ni t’e ba de’be
E ba mi ki won o
Gbogbo wa la o f’ayo de ‘le
Gbogbo wa la o f’ayo de ‘le wa
Mo ni t’e ba ri o
E ba nki Awero yen o
Omoge awelewa to nda ni l’orun o
Ile owo ni o wo s’aya
Ile ola ni o wo s’aya o

Seb’ade ori oko ni won
Obinrin to n’iwa t’o l’ewa
Iwuri obi ni won o ma je
Mobinrin to gb’eko to mu lo
Ori re dara, ori re sunwon, o d’adufe olori oko
Ori re dara, ori re sunwon, o d’abefe oIkoko to fo i s’oun a mu se’be

Ikoko to fo i s’oun a mu to’le
Ikoko to fo i s’oun a mu r’odo
Ikoko to fo i s’oun a mu yan’gan
Ibadi aran d’eni a mu se yeye o
Bi eye ti o l’apa
Ibadi aran d’eni a mu se yeye o O ba ma i lo o
O ba ma i lo o
Duro se’un obinrin nse
O ba ma i lo o
Awero o ba ma i lo o
Gb’aye se’un obinrin nseO ba duro f’inu sh’oyun
Duro se’un obinrin nse
O ba gb’aye feyin gbomopon
Gb’aye se’un obinrin nseO ba ma i lo o
O ba ma i lo o
Duro se’un obinrin nse

Ilu Orita o
Ilu alaafia
Mo ni t’e ba de’be
E ba mi ki won o
Gbogbo wa la o f’ayo de ‘le
Gbogbo wa la o f’ayo de ‘le wa
Mo ni t’e ba ri o
E ba nki Awero yen o
Omoge awelewa to nda ni l’orun o
Ile owo ni o wo s’aya
Ile ola ni o wo s’aya o

You can download many other Nigerian old school songs (1960-2003) here and old school hip hop music here. Click here to download all Nigerian throwback songs.

Cite this article as: Teslim Omipidan. (March 30, 2022). Download Ikoko Akufo – Beautiful Nubia. OldNaija. Retrieved from https://oldnaija.com/2022/03/30/download-ikoko-akufo-beautiful-nubia/

Artist

Leave a Reply. OldNaija loves your comment.

Back to top button